Oro Olorun To Mu Ni Lara Da


Si gbogbo awon ti ko ti ma gbadun igbe aiye ti o dara pelu Olorun ohun ti oye ki amo ni pe, Olorun ni emi aaye, ninu re ko si iku Esu ni eni iku, ati ninu re ko si iye, Olorun ti fun wa ni igbe aiye ti o dara, olukuluku si mu ipa tire, eniti abi sinu aiye yi, a nmu asi tun nje gbadun emi aaye yi pelu. Oh, iru aiye ti o dara wo ni iba wa fun awon ti ko ni iye meji, tabi ero miran, bawo ni iba ti dara to ki enia kan ma rin kiri oju ona tabi ki o rin ni oju ona orile ede, lati lo ri awon ododo ti o dara tabi bi agbegbe ibe ti seri, gbogbo won ngbe aiye ati aaye to odara pelu awon ebi, atipe gbogbo anfani ti a fun enikokan owa lati owo Olorun, lati ni alafia, lati inu ara re wa, Laisi igbasibi tabi sohun iye meji laisi idamu iye meji, laisi ilosiwaju aisan ninu ara re, ero yi le gbe o soke nipa emi re ki osi mu ayo wa fun o.

Looto, ati so lati enu oluko iwe pe, Enyin o si fi ayo fa omi jade lati inu kanga igbala wa. E lo si enu ona re ti enyin ti ope ati si agbala re ti enyin ti iyin. Bibeli so fun wa wipe, Inu didun mu imu larada rere wa, sugbon ibinuje okan mu egungun gbe. Aso fun wa lati enu eniti okowe pe, sugbon ibanuje ti aiye ama sise iku. Enikeni leri dada iditi Bibeli fi kowa ati ma sin Olorun ni ayo, alafia, ati ododo ninu emi mimo. Eleyi ni igbagbo ninu oro ileri re ati ni aimo so ododo ninu oro ti ko le kuna lati inu alope si alope ti ko le yi pada ti omu iye ainipekun wa. Awon oro ti mo ti so fun yin, emi ni iye si ni ileri igbekele ati ifihan idariji, enikeni ti o ba si fe ki ogba omi iye ne lofe won je ileri iwosan fun gbogbo enia, gege bi igbagbo won, ki o ri fun yin gege bi igbagbo yin. Laise ojusaju enikeni sugbon fi ola fun gbogbo enia gege bi eniti ada lati odo Olorun atele ona ara wa Bawo ni enikan ti se le ma gbadun gbogbo aiye, ona kan soso lowa Olorun ko fun wa ni emi iberu. A o biwa pelu iberu sugbon emi esu ni owa si okan wa nipa aigbagbo ninu oro Olorun ati ninu ileri re ti o dawa ti o si tun ya wa soto ninu aiye.

Jesu wipe, emase jeki okan yin daru tabi ki eru bayin. Oti to fun wa lati lo awojiji igbe aiye lati jeki a ni igbagbo ti ndagba ninu oro ti Olorun da, nigbati okan wa si ni igbagbo ti ati so pomo ero wa, bakan na emi Kristi na ni igbagbo ti ati pin fun gbogbo ijo gege bi Olorun ti fun won ni emi Kristi. Anilati wa oro ati ni igbagbo Jesu. Paulu wipe sugbon awa ni inu Kristi, sugbon ani lati gba laiye. Nipa iru ero ti owa ninu emi ati okan wa Olorun fi aaye fun gbogbo ohun ti oni ninu agbare re nipa emi yi sinu ara re bi igbala, iwosan, etc.

Ijoba Olorun mbe ninu wa nipa bayi, iwosan nbe lodo wa bakanna ni igbala wa. Paulu wipe ara Kristi ni awa ise. Opolopo nsun won kuna lati mo eleyi. Jesu ti di aisan re, ati fi iya je, nipa iku ori agbelebu ki iwo papa le di ara re ki ole bo patapata kuro lowo ese ati aisan ose eleyi nipa igbagbo ninu iku Jesu, oku ni ipo re. Kio le diara re ninu igbe aiye re. Nigba ti oba gbagbo pe, oti ba yi aiye pada lotito lesekese wa ri iwo san. Nigba gbogbo ma ranti pe ara re ti wa labe egun ofin ati dajo Olorun lati odo Mose ati kan lori abgelebu, nigbati oti wa di ara Kristi oti bo labe egun ofin nipa igbagbo ninu Jesu Kristi. Ileri Olorun ati gbogbo ipinu re je ti Jesu Oluwa. Anri gbogbo re gba nipa igbagbo ninu Jesu. Nipa gbigbagbo pe ara Jesu niwa omu ki ileri na je tiwa, ranti igbagbo wa nipa eko ti a to ninu oro Olorun, oro Olorun wa ninu okan Kristi igbagbo wa nipa gbigbo oro Olorun igbagbo Kristi je eyiti ojinle ninu okan tabi emi wa, Lati gbagbo adi eni igbala tabi iwosan, erokero je nigba ti antan ara waje tabi padanu, oni lati je idarudapo ninu emi ati okan wa. Nitori, okan la fi igbagbo si ododo.

Nitoripe bi oti nsiro li okan re be li ori. Jesu wipe ti oba le gbagbo li okan te ti oko siyemeji, ohun kohun ti iwo ba bere e ti ri won gba. Okan ko le gbagbo looto, ayafi ti oba yipada nipa ifi ara re sile ati ni fifi ara re sile fun Olorun, idi niyi ti igbagbo laisi ise fi je oku ise re nso igbekele ninu ore ofe Olorun ji. Igbagbo Kristi si o je idagba soke ti emi nigbati ogbon marun ti owa ni ara re (oju, enu eti imu, ati imo ohun ninu ara) ba ku nipa awe ati ise, Esu ko ni aaye lati sise, ti a ba ti le jade ninu re ayafi nipa ogbon re mararun ni ole di igbagbo re lowo, Nigbati oti ye wa bayi, eje ki a fi kun igbagbo wa nipa gbigba oro ileri re siwa.

Sugbon Olorun mi yio pase ni kikun fun gbogbo ainiyin gege bi oro re ninu ogo, ninu Kristi Jesu. Ranti boya nipa ti emi, nipa ti ara, ati nipa inawo yio fi gbogbo re fun o, Emi ni Olorun eniti odari gbogbo ese re ji eniti osi tan gbogbo arun re. Di eleyi mu owipe emi osi tan gbogbo arun kuro larin re. Olorun ni iye ati ohun gbogbo ti oro mo iye, gege bi iwosan, igbala, ayo, Alafia, ati igbadun, eleyi ti o je ti emi ati iye ati iye ati ara Kristi, ara eniti iwo ise, Jesu wipe emi wa ki iwo ki o le ni iye. Lati ro nipa eleyi je okan igbagbo ninu Kristi nipase ohun gbogbo ti anrigba lofe, yio ha ti se, ti ki yio fun wa li ohun gbogbo pelu re lofe.

Emi esu ni iku ti ise ota Olorun oro Olorun so fun wa pe, iku wa ni pase okunrin kan. Awon ohun ti iku nmu wa ni iberu, ibanuje, iponju, idamu, ikanu, ati aisan, gbogbo awon wonyi je ota Olorun, Kristi wa nitori awon nkan wonyi, iko ife, iba, kuruna, ifoju, owo riro, ese riro, iditi ati gbogbo aisan ti ako ko sinu iwe ofin yi gbawala kuro lowo won nitori won wa labe egun Olorun. A ti wa labe ore ofe Kristi ti ra wa pada, oti ra wa pada kuro lowo egun ofin nipa ara re lori igi. Gbogbo aisan ati arun ni gbogbo aiye wa nipase ese. Ese yi je aigbagbo nipa oro Olorun, Efa papa da ese yi. Ohun ti ko ba tinu igbagbo wa, ese ni. Adamu fi gbogbo enia sabe egun nipa aigbagbo Kristi ra gbogbo enia pada labe egun pelu igbagbo, nipa Adamu gbogbo enia ku, nipa se Kristi gbogbo enia di alaye. O si ran oro re eyiti o di (Jesu) o mu won larada. Igbagbo ninu oro re eyiti odi ara, A di oro na, ti ako si wa li okan ti gbogbo enia ti mo ti won si nka. Oro Olorun di ara a si je okan pelu oro na, gege bi ara kan pelu Kristi ko si aisan ninu Olorun, nipa ina re ni a mu wa larada.

Ani iru ara Kristi. Nwon segun esu nipa eje odo aguntan na ati nitori oro eri won, nwon ko si feran emi won ani titi de iku. Jijewo ninu oro ati ise, ohun ti oti se fun won, fi gbogbo aiya re gbekele oluwa, ma si se te si imo ara re. Awa nso gbogbo ero kale ati gbogbo ohun giga ti ngbe ara re ga si imo Olorun, awa si ndi gbogbo ero ni igbekun wa si iteriba fun Kristi. Iberu, Iyemeji nitori ero ti ara, ota ni si Olorun, nitori ki iteriba fun ofin Olorun, oun ko tile lesee. Olorun ki yio yi ohun ti o ti ete re jade pada, nitori yio kiyesi oro enu re lati mu se. Ti oba se pe nipa ina re ni afi mu wa larada, ti ko si ka enikeni si ani lati pe awon nkan wonyen ti ki se, bi won otile je nipa igbagbo, sugbon olododo ni yio ye nipa igbagbo papa igbagbo re ti mu o larada.

Olorun so fun wa ninu oro re pe, oun ju ohun gbogbo lo, ki o se rere ki osi wa ni ilera, ani bi oti dara fun okan re. Oluwa ni Olorun re ti ofun o lagbara lati ni oro. Oni lati fi oro re nibiyi fun ise oluwa nipa siparo fun oro ti iye ainipekun. Gbagbo (ranti idaru okan) pe aisan re looto, daju pe oti lo ko le kuna nigba kan. Oni lati ni igbagbo ole wa pelu aisan ati idamu sugbon ti oba gbagbo lotito yio gba isakoso ara fi diwon si ise ti ododo papa nipa ifihan. Olorun koje fi wa sile be ni ko ke ko wasile. Olorun ki kuna anfi sile nipa aigbagbo.

Johanu wipe eyi ni igbekele wa ninu re ohunkohun ti aba bere nipa oruko re anri gba bi Okan wa ko ba da wa lebi nje awa ni igboya niwaju Olorun. Paul wipe ninu eyi li emi si nse leti araye lati ni eriokan ti ko li ese sipa ti Olorun, ati si enia nigbagbogbo gege bi iwe mimo ti wi enikeni ti obere nrigba. Bi enyin ba bere ohun kohun li oruko mi emi o see, Jesu so kale yin Baba ti mbe lorun logo, Ebere ki ayo yin ki ole kun. O gba ailera wa o si ru arun wa lori igi ati pe nipa ina re lafi mu wa lara da. Jesu wipe o pari. Nigba ti oti gba ailera re si ara re ki lode ti otun fi nwa won nitori iro esu, Ranti pe igbagbo ni imo lati fi ero tire ati ise re sile. Nipa gbigba ero re gbo oun ni lati se ero ara re ati irewesi okan lati ni ero ti ko sise nipa ileri re, yio mu kuro lati inu okan re owo jiji isegun, yio si mu idunnu, ilera ati igbadun si ona re ti oba ti dawo igbagbo duro, odawo ise duro, nigbagbo ma kiyesi ero ati igbe aiye re sugbon ki e parada lati di titun ni iro inu yin. Gbe okan re toto duro, (Okan Kristi) ki o si yanju eyi ti odara ti o si se itewogba ife ti Olorun, oun ti olori alufa ti ko le saiba ni kedun ninu ailera wa. Se alabapin ipe orun ninu okan re ki ole je alabapin ipe orun. Nitori okan li afi igbagbo si ododo enu li a si fi ijewo si igbala. Jewo ki o si gbagbo, gbaa ki o si di mimo ni oruko Jesu Kristi kuro ninu gbogbo aini, aisan ati gbogbo idamu re ki Olorun ki o bukun o ni adura mi.

Rev. George Leon Pike Sr.

Founder and first President of Jesus Christ’s Eternal Kingdom of Abundant Life, Inc.

Iwa Mimo Si Oluwa

Ise iranse yi wa fun pipin lofe fun awon iwe miran, kowe si adiresi ti owa ni isale yi, ati iye eyiti ole lopelu ogbon.

YOR9908T • YORUBA • GOD’S HEALING WORD